IWOSAN FUN ITO SUGAR (DIABETES)

Aku Ojumo o!
Iwosan Ito Sugar ti an pe ni Diabetes ni ao menuba leni, ema bawa kalo.

A o wa ewe efirin nla, ewe guova, ewe ejinrin, a o ko gbogbo re sinu Koko, a o bu omi(clean water) si ao se daada. Leyin Ose meji, ti a tiun lo agbo yi daada, ni owuro ati asale. Pelu Ogo olohun, won o ni ri sugar kankan lara wa biotiwu ki o kere mo ti won ba lo pada se ayewo ni ile iwosan. O daju.

Comments

Unknown said…
nice one bro.....keep it up
Unknown said…
Barakah lahu fihi bro
Atadek said…
Aamin, Waiyak, thank you all
Unknown said…
Moni igbagbo wipe yioo side fun okomi. Thanks so much
Unknown said…
Ewe efirin nla ........is it normal efirin
Atadek said…
Yes, but big one

Popular posts from this blog

EWE ORUWO( Solution to several aliments)

Malaria herb solution (Agbo Iba)