Aku Ojumo o! Iwosan Ito Sugar ti an pe ni Diabetes ni ao menuba leni, ema bawa kalo. A o wa ewe efirin nla, ewe guova, ewe ejinrin, a o ko gbogbo re sinu Koko, a o bu omi(clean water) si ao se daada. Leyin Ose meji, ti a tiun lo agbo yi daada, ni owuro ati asale. Pelu Ogo olohun, won o ni ri sugar kankan lara wa biotiwu ki o kere mo ti won ba lo pada se ayewo ni ile iwosan. O daju.
Comments