A o se ewe ipin pelu omi dun(Corn/Pap water), ti oba ti loworo(warm but not hot) diee, a o wa mu ni owuro,osan, ale. Sugbon, Agbo yi fun ojokan ni a o ma mu, ti o ba tun di Ojo keji a o tun se ewe ipin mi pelu omidun.
As I wrote in my previous post that this plant(Ewe Oruwo) cures several ailments, Indeed! It is also ideal for diabetic in reducing and regulating sugar level in the body system, possibly due to its intense bitterness. This said plant can be used for general purpose (Gbogbo nise) particularly for malaria issue, Usage; kindly squeeze ewe oruwo leaves with clean water and sieve(by removing particles from the liquid solution) , then drink the result. It will be whaostic in your body system. Stay healthy and be cool....ILERA LOOGUN ORO......watch out for more.....
Aku Ojumo o! Iwosan Ito Sugar ti an pe ni Diabetes ni ao menuba leni, ema bawa kalo. A o wa ewe efirin nla, ewe guova, ewe ejinrin, a o ko gbogbo re sinu Koko, a o bu omi(clean water) si ao se daada. Leyin Ose meji, ti a tiun lo agbo yi daada, ni owuro ati asale. Pelu Ogo olohun, won o ni ri sugar kankan lara wa biotiwu ki o kere mo ti won ba lo pada se ayewo ni ile iwosan. O daju.
Good Morning everyone. Today, I am going to be codemixing languages for the benefit of those who don't really understand Yoruba. Herb solution for MALARIA(Agbo Iba): Kindly pluck pawpaw leaves(Ewe ako ibepe) and squeeze with milk(especially with Peak milk, meaning Miliki Olope in yoruba) or 7 up and drink the liquid part after been sieved(I.e- after removing the particles).